Jakejado agbaye lawọn ọmọ Naijiria tọmọde tagba ti n fi itan lelẹ nipa orisirisi igbiyanju wọn. Ninu wọn la tun ti ri ọdọmdekunrin ọdun mẹwaa kan Tanitoluwa Adewumi to gbegba oroke lati di Chess ...