Ẹgbẹ adaranjẹ ti a mọ si Miyetti Allah Cattle Breeders Association of Nigeria (MACBAN) ẹka ti Ipinlẹ Kwara, ti ke si ijọba ipinlẹ náà ati awọn agbofinro lati kilọ fun awọn ti wọn n pe awọn ni agbébọn, ...